First Term Yoruba Examination Question for Primary School
Yoruba Exam Questions for Primary School First Term – Edudelight.com
FIRST TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KINNI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:-
- Leta A ni o bere oro? (a) kalamu (b) Aja (d) Igbin
- Apeere sise nnkan ni _____ (a) patewo (b) omode (d) sibi
- Bawo ni a se ki eniyan ni aaro (a) e kaale (b) e kaaro (d) e kaasan
- Kini a fi n fo enu wa? (a) obe (b) iwe (d) Buroosi
- Nje o dara ki a maa sere ninu ojo? (a) o dara (b) ko dara (d) n ko mo
- Ipo wo ni obinrin gbodo wa ti won ba n ki agbalagba ni ile Yoruba. (a) obinrin maa n sun (b) obinrin maa n salo (d) obinrin maa n kunle
- Ojo meloo ni o wa ninu ose (a) ojo meta (b) ojo meje (d) ojo mewa
- Kini 2 ni onka Yoruba? (a) meji (b) merin (d) mefa
- Tani olori ebi? (a) baba (b) iya (d) egbon
- Apeere iwa rere ni (a) suuru (b) ole jija (d) ija jija
So oruko awon aworan wonyi
11.
(a) ese (b) apa (d) ori
12.
(a) iwe (b) moto (d) aso
13.
(a) ewure (b) Adiye (d) Aja
14.
(a) tabili (b) Igbale (d) Bata
15.
(a) Ile (b) moto (d) Abo ounje
IPIN KEJI
Ko leta alifabeeti lati ori A-Gb
___________, ____________, _____________, ____________________
___________, ____________, _____________, ____________________
So awon onka wonyi papo pelu leta ti o ye
First Term Yoruba Examination Question for Primary School
FIRST TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:-
- Ori ibo ni a maa n sun si ? (a) ori beedi (b) ori telifisan (d) ori odo
- Bawo ni a se n ki eniyan ni osan (a) e kaasan (b) e kaale (d) e kaaro
- Bami na omo mi, ko denu ____(a) olomo (b) tisa (d) ode
- Kini ohun elo inu ile ti a fi n joko? (a) pootu (b) Aga (c) sibi
- _____ lo le segun arun gbogbo (a) ewure (b) efon (d) imototo
- Kini ogbon ni nomba (a) 40 (b) 30 (d) 50
- Leta faweeli meloo ni o wa? (a) meta (b) meje (d) mewa
- Kini ohun elo inu ile ti a fi n gbale? (a) Igbale (b) Ada (d) Obe
- _____ ti ko ninu, oluwa lo ba n le esinsin (a) iyawo (b) maluu (d) Adiye
- Ipo wo n I obinrin maa n wa ti won ba fe ki agbalagba ni ile Yoruba (a) obinrin maa n sare (b) obinrin maa n sun (d) obinrin maa n kunle
- Kini 25 ni onka Yoruba (a) Aarundinlogbon (b) aarundinlogoje (c) Aarundinlogota
- Apeere sise nnkan ni ___(a) patewo (b) iwe (d) obe
- Bawo ni okunrin se maa n ki agbalagba ni ile Yoruba (a) okunrin maa n fo (b) okunrin maa n dobale (d) okunrin maa n salo
- Bawo ni a se n ki eniyan ni ale (a) e kaale (b) e kaasan (d) e kaaro
- Inu ibo ni a ti lee ri omi tutu (a) inu gaasi (b) Inu pootu (c) inu firigi
- Kini oruko awon ore meji wonyi (a) Aja ati elede (b) Ijapa ati Aja (d) Adiye ati Obo
- Tani o mu ijapa lo si oko ole ? (a) Aja (b) Obo (d) Ewure
- Kini won lo ji (a) ata (b) ewa (d) isu
- Tani oloju kokoro ninu awon ore wonyi? (a) Ijapa (b) aja (d) Elede
- Kini Oba se fun Ijapa? (a) Oba na (b) Oba pa (d) Oba be
IPIN KEJI
1.Dahun gbogbo awon awon ibeere wonyi?
Ko gbogbo leta faweeli jade
i. …………………………….ii……………………..ii…………………….
iv………………………………v…………………vi………………………..
vii………………………………..
B. So awon onka wonyi papo pelu nomba ti o ye
First Term Yoruba Examination Question for Primary School
FIRST TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KETA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:-
- Nje o dara ki a maa rin pelu akiyesara loju popo? (a) beeko (b) Beeni (d) nko mo
- Kini ami yii + ni ede Yoruba (a) Aropo (b) Ayokuro (d) pinpin
- Kini 40 ni onka Yoruba (a) ogbon (b) aadota (d) ogoji
- Kini o le segun arun gbogbo? (a) ewure (b) imototo (d) adajo
- Wara ko si loni, wara n be ___(a) ninu pootu (b) ninu omi (d) lola
- Tani olori ile (a) Baba (b) Iya (d) Aburo
- ______ ni ege oro ti o lee ba eemi jade leekan soso (a) faweli (b) silebu (d) konsonanti
- Silebu meloo ni o wa ninu Ade (a) meji (b) ookan (d) merin
- Iwa ole jija ko dara (a) beeko (b) Beeni (d) n ko mo
- Nje o dara ki a maa soro ti a ba n jeun lowo (a) ko dara (b) n ko mo (d) o dara
Ninu itan Ijapa ati aja
- Kini oruko awon ore meji wonyi (a) Aja ati elede (b) Ijapa ati Aja (d) ewure ati Igbin
- Tani o mu ijapa lo si oko ole? (a) elede (b) kiniun (d) Aja
- Kini won lo ji ni Oko oloko (a) ata (b) ogeed (d) isu
- Tani o ranse pe aja? (a) oba (b) olopa (d) ijoye
- Kini won se fun Aja? (a) won na (b) won bu (d) won pa
Ka awon gbolohun wonyi, ki o so dahun ibeere ti o tele
Omosalewa je ogeed
Agbe gbin isu
Baba agba sun
Asa gbe adiye ojo
Yemisi rerin in
Toyin fo soke
Ebi n pa bosede
- _______ni o je ogeed (a) baba (b) iya (d) omosalewa
- Kini agbe gbin? (a) ogeed (b) ibepe (d) osan
- ____________lo rerin-in (a) Toyin (b) Yemisi (d) Abiosun
- Kini baba agba se? (a) o sun (b) o fo soke (d) o salo
- Tani ebi n pa? (a) Bola (b) Tayo (d) Bosede
IPIN KEJI
1. Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:- Pin awon oro wonyi si silebu
i. baba :- __________________ ii. iwe :- __________________
iii. aga:-_________________iv. Oba -____________________
v. meji:- __________________
2. ko onka wonyi ni nomba
i. Ookanlelogbon __________________ ii. Eetalelogoji _______________
iii. Aarundinlaadota ________________ iv. Aadota__________________
iv. Eejilelogoji____________________________
v.Ogun____________________________
Sipeli
Yoruba Exam Questions for Primary School First Term – Edudelight.com
FIRST TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KERIN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:-
- Ami ohun meloo ni o wa? (a)meji (b) mewa (d) meta
- ____ je apeere iwa omoluabi (a) ifarada (b) ole (d) ole jija
- Apeere ise ile ni ____(a) ija jija (b) imele sise (d) aso fifo
- _____je ibasepo laarin okunrin ati obinrin ti o ti balaga gege bi oko ati aya pelu ifowo sowopo awon ebi mejeeji (a) igbeyawo (b) ijiroro (d) igbese
- Orisii igbeyawo meloo ni a menuba (a) meji (b) merin (d) mefa
- Nibo ni orison iwa omoluabi (a) eko ile (b) oko (d) oja
- Aroko ti o da lori iyan jija ni ____(a) aroko onileta (b) aroko alariyanjiyan (d) aroko oniroyin
- _____ je okan lara ohun elo idana (a) beedi (b) ewe (d) obi
- Omobinrin wulo ju omokunrin lo je apeere aroko ___ (a) asapejuwe (b) ariyanjiyan (d) ajiroro
- Awon wo ni o maa n se igbeyawo soosi (a) musulumi (b) kiristeni (d) Alawo
- Do je ami ohun ____(a) ami ohun isale (b) ami ohun oke (d) ami ohun aarin
- Nje o ye ki a maa bowo fagba? (a) beeni (b) beeko (d) N ko mo
- Kini itumo agbeko? (a) awotele obinrin (b) nnkan ti a ko ti (d) ohun ti a gbeko sori igi
- Itumo Aafin ni ____(a) ile ijoba (b) ile ejo (d) ile Oba
- Itumo ogun ni ____(a) dukia ti a jogun (b) oruko ilu (d) orisa irin
- Owo tumo si ______(a) iyi (b) oruko oja (d) Igbale
- Ise oluko je mo ___(a) iwosan (b) eko kiko (d) oko riro
- Ise agbe je mo ___(a) ipese irugbin , eran osin ati eja sinsin (b)
- Ise agbe ati oluko ____Ni awujo (a) baje (b) ko dara (d) wulo
- Ami ohun aarin ni ___(a) do (b) re (d) mi
- Kini oruko awon ore mejeeji wonyi (a) toriola ati rolawe (b) toriola ati tope (d) rolawe ati akin
- Tani omo orukan ninu won (a) toriola (b) tope (d) rolawe
- Tani o ran toriola lowo ti o fi pari ile eko girama? (a) Obi Rolawe (b) olopa (d) Oba
- Odo tani Toriola n gbe (a) odo iya re (b) odo ana re (d) odo ibatan re
- Kini oruko iyawo Biodun (a) Tooke (b) Idowu (d) Alaba
- Ise wo ni Abiodun n se (a) ise oluko (b) ise atunnase (d) ise fayawo
- ________ni oga asobode tuntun (a) Idowu (b) Rolawe (d) Toriola
- Nje o dara ki a maa se aanu omolakeji (a) Beeni (b) Beeko (d) N ko mo
- Iwa omoluabi maa n je ki _____ rorun ni awuyo. (a) ibara eni gbe po (b) ole jija (d) ija igboro
IPIN KEJI: Dahun gbogbo awon ibeere wonyii:
Daruko marun-un ninu ohun elo idana
i. ______________________________ ii. _____________________
iii. ______________________________ iv. _____________________
v. _______________________________
ko orisii ami ohun ti o wa sile
- ___________________ ___________________
- ____________________
Daruko orisiirisii igbeyawo meji .
i. __________________________________
ii. _________________________________
Apeeko
i. _______________________ii. _________________________________
iii. ___________________________iv. ______________________________
v._____________________________vi. __________________________________
vii. ______________________________ viii . ___________________________
ix. __________________________________x. _______________________________
Yoruba Exam Questions for Primary School First Term – Edudelight.com
FIRST TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KARUN-UN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:-
- ______ je okan lara ona ibanisoro ni aye atijo ni …. (a) ilu (b) ijo (d) obe
- Apeere iwa omoluabi ni ___(a) ibowofagba (b) ole jija (d) imele sise
- Ojo kelo niyoruba maa n so omo loruko ni ode oni (a) ojo kejo (b) ojo kewa (d) ojo kejila
- Kini 120 ni onka Yoruba (a) ogota (b) ogoje (d) ogofa
- …..je okan lara ohun elo isomoloruko (a) ataare (b) aso (d) ikoko
- Okan ninu ohun elo ibanisoro aye ode oni ni (a) telifoonu (b) aga (d) beedu
- Aso okunrin ile Yoruba ni ___(a) iro (b) yeri (d) agbada
- Oba waja tumo si _____(a) oba salo (b) oba ku (d) oba de
- Laali lile je asa _____ni ile Yoruba (a) oge sise (b) alo pipa (d) owe pipa
- Ojo isomoloruko fun awon ibeji ti won ba je obinrin meji ni (a) ojo kesan (b) ojo keje (d) ojo kefa
- Eni to n dari eto isomoloruko ninu idile ni (a) baba omo (b) Baale ile (d) iya omo
- Ninu ___ ni iwa Omoluabi ti jade (a) imototo (b) Eko ile (d) Ofin
- Apeere iwa ti ko dara ni (a) aanu (b) iro pipa (d) irele
- Awon wo ni o maa n di irun ni ile Yoruba? (a) obinrin (b) okunrin (d) Arugba
- Aroko wo ni o maa n dale iyan jija (a) Aroko onileta (b) Aroko oniroyin (d) aroko alariyanjiyan
- Ona ti omode fi le bowo fagba ni ___ (a) Nipa kiki ni (b) Nipa bibu ni (d) Nipa ni na ni
- Ise agbe dara ju ise oluko lo je apeere aroko ___(a) aroko oniroyin (b) aroko asapejuwe (d) aroko alariyanjiyan
- Bami na omo o mi, ko denu olomo je apeere ___(a) girama (b) owe (d) akanlo ede
- _____ ni ohun ti a ro, ti a si ko sile (a) aroko (b) aroso (d) adako
- Apeere ila kiko ni ile Yoruba ni ___(a) abaja (b) soro (d) owe
- Ipinle wo ni a ti lee ri ijebu ___ (a) ipinle oyo (b) Ipinle ondo (d) ipinle ogun
- Apeere oruko amutorunwa ni ___(a) Dada (b) kike (d) sule
Ninu itan ti a ka ninu iwe kika wa. ODEBIYI AKIKANJU OKUNRIN
- _____ ni oruko ilu yi (A) Bioku (b) Badeku (d) Apomu
- Awon ___ni o maa n yo awon eniyan lenu ninu ilu yii (A) ode (b) olopa (d) ode
- Ise __ ni Odebiyi n se niluu yii (a) Agbero (b) Ode (d) Awako
- Tani o papa mu awon ole yii (a) Odebiyi (b) Bolanle (d) Adebisi
- Irun gige je asa oge sise laarin awon ___(a) Adajo (b) okunrin (d) obinrin
- Kini ogoje ni nomba (a) 100 (b) 140 (d) 120
- Apeere aso obinrin ile Yoruba ni ___(a) Sokoto (b) Kembo (d) iro
- Ojo keloo ni a maa n so omokunrin ni oruko ni aye atijo (a) ojo kesan (b) ojo keje (d) ojo kejo
IPIN KEJI: Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
Daruko marun ninu aso okunrin ile yoruba
i. ___________________________ ii. _________________________
iii. ___________________________ iv. _________________________
v. ____________________________
So marun-un ninu ona ibanisoro ni aye ode oni
i. ___________________________ ii. _________________________
iii. ___________________________ iv. _________________________
v. ____________________________
Sn
o ona marun-un ti awon Yoruba n gba soge ni aye atijo
i. ___________________________ ii. _________________________
iii. ___________________________ iv. _________________________
v. ____________________________
Yoruba Exam Questions for Primary School First Term – Edudelight.com
FIRST TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KEFA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:-
- Kini 150 ni onka Yoruba? (a) Aadojo (b) ogoje (d) ogofa
- Orisun iwa omoluabi ni ____(a) eko ile (b) ijo jijo (d) alo pipa
- Orisii ise owo ni ile Yoruba ni ___ (a) ole jija (b) titoro owo (d) ise apeja
- Oruko eso ti a fi n ta ayo ni ____(a) omo ayo (b) ileke (d) efun
- Iya ati baba w ani ____(a) alufa wa (b) obi wa (d) lemonu
- _____ je oro oruko eranko (a) aja (b) ogeed (d) igbale
- Eyin pipa je okan lara asa ___ni ile Yoruba (a) ako sise (b) oge sise (d) ole sise
- Eniyan meloo ni o maa n ta ayo leekan soso? (a) eniyan meta (b) eniyan kan (d) eniyan meji
- Awon onise wo ni o n gbin ounje ti a n je (a) alagbede (b) onidiri (d) agbe
- Kini oruko oba ilu oyo (a) osemowe (b) Alaafin (d) awujale
- Kini oro oruko ninu gbolohun yii “Bola sun” (a) Bola (b) sun (d) n ko mo
- Oro oruko n sise _____ ati ____ ninu gbolohun (a) iya ati baba (b) oluko ati akekoo (d) oluwa ati abo
- Tani Yoruba n pe ni alapa-ma-sise? (a) gbajumo (b) ole (d) agbe
- Okan lara ohun elo fun alaro ni (a) ikoko aro (b) aake (d) ada
- Ise to bori gbogbo ise miran ni ise ____(a) aso hihun (b) ope kiko (d) ise agbe
- Nnkan elo aludun ti awon Yoruba n lo fun ibanisoro (a) ilu (b) iwe (d) sekere
- _____ ki I se ilu ibile Yoruba (a) gangan (b) bata (d) konga
- Ohun ____ni ilu Yoruba fi maa n soro (a) meta (b) meji (d) mejo
- Yiyan ni ___maa n yan oro oruko (a) epon (b) eyan (d) aropo
- Eyan asonka ni ____(a) gogoro (b) banba (d) mejo
- Eyan asafihan ni ____(a) mefa (b) yii (d) kabibi
- Aajo ewa ni ___(a) ikini (b) ilera (d) oge sise
- Oge sise wa fun ___(a) tajateran (b) tokunrintobirin (d) tekuteye
- Yato si oge sise ____tun maa n fo idoti kuro ninu eyinju (a) laali (b) ara siso (d) tiroo
- Aboruboye la n ke ____(a) amokoko (b) Babalawo (d) alaro
- Bawo ni a se n ki onidiri (a) oju gbooro (b) adepa (d) igba aro
- Ona ti awon yoruba n gba se iranlowo fun ara won laye atijo ni ___je (a) asa oge sise (b) asa rar finfin (d) asa iranra-eni -lowo
- Ilo meloo ni o wa ninu opon ayo (a) mejila (b) meta (d) mewa
- Fese fe tumo si ______(a) sun (b) salo (d) jeun
- Ohun elo fun ise agbe ni ____(a) ada (b) emu (d) igba
IPIN KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi.
A. so apeere oro oruko marun
i. ______________________________ ii. ________________________
iii. ___________________________iv. __________________________
v. _________________________
B. Daruko ona marun ti awon Yoruba n gba ran ara won lowo
i. ______________________________ ii. ________________________
iii. ___________________________iv. __________________________
v. _________________________
D. Daruko marun ninu ise ti a n se ni ile Yoruba (ise abinibi ile Yoruba)
i. ______________________________ ii. ________________________
iii. ___________________________iv. __________________________
v. _________________________
E. Ko awon nomba wonyi ni nomba
i. ogofa : – ______________________ (ii) igba/aadowa:- ____________
iii. ogoje – _____________________ iv. Aadofa:- _________________
v. Ogorun:- _______________






