SECOND TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA JSS3 (BASIC 9)
Junior Secondary School Curriculum Yoruba – Edudelight.com
NERDC Curriculum Yoruba JSS3
JSS3 Second Term Yoruba Curriculum Lagos State
Week 1
EDE – Ihun orisirisi awe gbolohun po lati di odidi gbolohun
ASA – Awon asa to suyo lati inu awon ewi alohun
LITIRESO – Kika iwe literaso apileko ti ijoba yan
Week 2
EDE – Atunyewo leta kiko (aigbefe)
ASA – Awon oriisa ati eewo to suyo ninu litireso alohun ti a n fi oro inu won daa mo LITIRESO – Ifaara lori litireso alohun
Week 3
EDE – Iyato ti o wa laarin apola ati awe gbolohun Yoruba
ASA – Itan isedale agbala aye
LITIRESO – Kika iwe litireso apileke ti ijoba yan
Week 4
EDE – Aroka alalaye
ASA – Owe ile Yoruba
LITIRESO – Oriki orile elerin, olokun, esin, onikoyi, olofa abbl.
Week 5
EDE – Gbolohun Onibo
ASA – Awon akanlo oro inu ede ati awujo Yoruba
LITIRESO – Kika iwe apileko ti ijoba yan
Week 6
EDE – Akaye oloro wuuru / geere
ASA – Awon orisa to suyo ninu litireso
LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan
Week 7
EDE – Akaye II (Ewi)
ASA – Awon imole / orisa to suyo ninu litireso
LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan
Week 8
EDE – Atunyewo awon oro eyan
ASA – Igbese igbeyawo ni ile Yoruba
LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan
Week 9
EDE – Atunyewo awon oro aponle
ASA – Ikomojade ni ile Yoruba
LITIRESO – Kika iwe apileko ti ijoba yan
Week 10 – Atunyewo ise lori ise saa yii lori ede, asa ati litireso
Week 11 – Idanwo ipari saa keji
Week 12 – Ifi – owo si iwe idanwo
JSS3 Second Term Yoruba Curriculum – Modified
1 [a] Èdè; Hìhun orisirisi awé̩- gbólóhùn pò̩ di odidi gbólóhùn
[b]Àsà; Àwo̩n àsà tó súyo̩ láti inú orin etíye̩rí àti dadakúàdà
[d]Lítírésò̩; Àkóónú orin etíyerí àti dadakúàdà
2 [a]Èdè; Àròko̩ lé̩tàkíko̩ – àìgbè̩fè̩
[b]Àsà; Àwo̩n orìsà àti èèwò̩ tó súyo̩ nínú lítírésò̩ Yorùbá
[d]Lítírèsò̩; Ìfáàrà lórí àwò̩n lítírésò̩ alohùn tí a ń fi ò̩rò̩ wo̩n dá
wo̩n mo̩.
3 [a]Èdè; Ìyàtò̩ tó wà láàrín àpólá àti awé̩- gbólóhùn Yorùbá
[b]Àsà;Ìtàn ìsè̩dálè̩ àgbáyé.
4[a]Èdè; Àròko̩ alálàyé 1: Ìtó̩nisónà àti àròso̩
[b]Àsà; Òwe Yorùbá
[d]Lítírésò̩; Oríkì orílè̩ – e̩lé̩rìn, olókùne̩sin abbl
5[a]Èdè; Àròko̩ alálàyé II
[b]Àsà; Àwo̩n àkànlò ò̩rò̩ Yorùbá
[d]Lítírésò̩;Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
6[a]Èdè; Àkàyé 1- o̩ló̩rò̩ wuuru/ geere
[b]Àsà; Àwón imo̩lè̩/òrìsà tó súyo̩ nínú lítírés̩o̩
[d]Lítírésò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
7[a]Èdè; Àkàyé II- Ewì
[b]Àsà; Àwón imo̩lè̩/òrìsà tó súyo̩ nínú lítírés̩o̩
[d]Lítírésò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
8[a]Èdè; Àtúnyè̩wò àwo̩n è̩yán ò̩rò̩
[b]Àsà; Ìgbésè ìgbéyàwó ní ilè Yorùbá
[d]Lítírésò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
9 [a]Èdè; Àtúnyèwò àwo̩n ò̩rò̩ àpó̩nlé
[b]Àsà; Ìkómojáde ní ilè̩ Yorùbá
[d]Lítírés̩ò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
10. Àtúnyèwò isé sáà kíní
11. Àtúnyèwò isé sáà kejì
12. Àtúnyèwò isé̩ lori ìwé lítírésò̩ tí ìjo̩ba yàn
13. Ìdánwo sáà kéjì
Ò̩sè̩ kíní-ín;
[a]Èdè; Hìhun orísìí awé̩-gbólóhùn pò̩ di odidi gbólóhùn
[b]Àsà;Àwo̩n àsà tó súyo̩ láti inú orin etíye̩rí àti dadakúàdà [d]Lítírésò̩; Àkóónú orin etíyerí àti dadakúàdà