Third Term Yoruba Examination Question for Primary School
Yoruba Exam Questions for Primary School Third Term – Edudelight.com
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KINNI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
1. Ori ibo ni a maa n sun si? (a) ori odo (b) ori sitoofu (d) ori beedi
2. Bi mo ba kawe mi ____ mi a dun koko ka (a) bata (b) iwe (d) obe
3. Apeere nnkan sise ni _____ (a) igi (b) dobale (d) aga
4. ____ ni o le segun arun gbogbo (a) imototo (b) beedi (d) rula
5. Nje o dara ki a maa a ja? (a) o dara (b) ko dara (d) n ko mo
6. Kini 11 ni onka Yoruba? (a) Eejila (b) Eefa (d) ookanla
7. Kini Aiku ni ede geesi? (a) Sunday (b) Tuesday (c) Friday
8. Obinrin maa n ___irun won (a) di (b) jo (d) sa
9. okunrin maa n ____irun won (a) se (b) ge (d) pin
10. Bawo ni a se n ki eniyan ni osan? (a) e kale (b) e kuurole (d) e kaasan
Kini oruko awon aworan wonyii:-
11. 12.
| (a) rula (b) foonu (d) iresa |
(a) obe (b) agogo (d) iwe
13. 14.
| (a) patako ikowe (b) igbale (d) abo ounje |
| (a) redio (b) telifisan (d) tabili |
15.
(a) tabili (b) aso (d) sibi
IPIN KEJI: Dahun awon ibeere wonyi . Ko leta alifabeeti lati ori A-S
a, ________, d , _______, e, _________, g, ________, h, ________,j, __________, i,_______, n, ______, o, _________, r.
| Eewa – 14 Ookanla – 15 Eejila- 10 Eetala – 12 Eerinla – 13 Aarundinlogun- 11 |
so onka wonyi papo pelu nomba ti o ye.
Yoruba Exam Questions for Primary School Third Term – Edudelight.com
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
1. Bawo ni a se n ki eniyan ni akoko oye (a) e ku idaraya (b) E ku otutu (d) E ku odun
2. _____ ni ege oro ti o lee ba eemi jade leekan soso (a) silebu (b) tabili (d) Aga
3. Kini o maa n sele ni igba ooru? (a) otutu maa n mu (b) ata maa n po (d) ooru maa n mu
4. ____ ti ko ni iru olorun lon ba a le esinsin (a) Aja (b) maluu (d) Elede
5. Kini o lee segun arun gbogbo (a) olopaa (b) imototo (d) akekoo
6. Leta wo ni o gbeyin ninu leta alifabeeti Yoruba (A) leta B (b) leta D (d) Leta Y
7. Silebu meloo ni o wa ninu baba (a) silebu kan (b) silebu meta (d) silebu meji
8. A maa n sun si ori ____(a) firigi (b) beedi (d) sitoofu
9. Ohun elo ti a fi n gbale ni (a) igbale (b) ose (d) agolo
10. N je o dara ki a maa so otito (a) beeni (b) beeko (d) n ko mo
11. ______ funfun ko mo ara re lagba (a) adiye (b) opolo (d) agutan
12. Bawo ni a se n ki eniyan ni ale (a) e kaaro (b) e kaasan (d) e kale
13. ____ n lota ileke n saso (a) baba (b) iyawo (d) omode
14. ____ je okan ninu ohun elo ile (a) telifisan (b) igi (d) reluwe
15. Apeere sise nnkan ni ____(a) gbale (b) sitoofu (d) taya
Ninu itan ijapa ati igbin ti a ka
16. Tani o lo mu erin wa lati inu igbo? (a) Ijapa (b) obo (d) elede
17. Kini ijapa so fun erin pe won fe se fun (a) won fe na (b) won fe fi je oba (d) won fe fun lowo
18. kini Ijapa fun erin je? (a) dodo (b) akara oloyin (d) eja dindin
19. Kini awon ara ilu se fun erin? (a) won na (b) won gbe (d) won pa
20. Nje o dara ki a maa se oju kokoro? (a) o dara (b) N ko mo (d) ko dara
IPIN KEJI
(A). Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
Ko leta alifabeeti Yoruba jade
A ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___
(B). Pin awon oro wonyi si silebu.
(1) Ada- ____________________
(2) Obe- ____________________
(3) Baba- ______________________
(4) Iya- ________________________
(5) ese- ________________________
(6) Ata- ________________________
(7) Bola – _______________________
(8) dodo – ___________________________
Yoruba Exam Questions for Primary School Third Term – Edudelight.com
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KETA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Apa ibo ni a ti gbodo maa rin ti a ba n rin ni opopona oko (a) apa osi (b) apa otun (d) nko mo
- Nje o dara ki a maa hu iwa rere (a) o dara (b) ko dara (d) n ko mo
- Awo dudun ni a n pe ni ___ni ede geesi (a) red (b) blue (d) black
- Kini o le segun arun gbogbo (a) owo (b) oba (d) imototo
- Kini a fi n gbale? (a) sibi (b) igbale (d) obe
- Kini ohun akoko ti a gbodo se ti a ba fe jeun? (a) sare (b) fo owo wa (d) fo ese wa
- Apeere ise owo ni ile Yoruba ni ___(a) ise alagbede (b) ise osu (d) ise panapana
- Kini o koja niwaju ile oba ti ko ki oba? (a) maluu (b) esinsin (d) ejo
- Kini Eetalelaadota ni nomba (a) 35 (b) 53 (d) 76
- Kini nomba yii 50 ni onka Yoruba (a) ogbon (b) ogun (d) Aadota
- Silebu meloo ni o wa ninu Ade? (a) mewa (b) merin (d) meji
Ninu itan ijapa : idi ti imu ijapa fi ku kanbo
- Kini oruko awon ore ninu itan yii? (a) ijapa ati okere (b) ijapa ati aja (d) aja ati okere
- Awon wo ni o n ja? (a) asin ati okere (b) Ijapa ati asin (d) oba ati aja
- Tani o ge imu ijapa je? (a) asin (b) okere (d) ekute
- Tani o n korin ninu itan yi (a) okere (b) asin (d) ijapa
- Oruko akoni ile yoruba ti a menuba ni ____(a) Oduduwa (b) Awolowo (d) tinubu
- Nje o dara ki a maa jale (a) ko dara (b) o dara (d) N ko mo
- Yara idana ni a n pe ni ____(a) bathroom (b) kitchen (d) toilet
- Ojuse obi si omo ni ___(a) sisan owo ile iwe (b) fifi omo se erun (d) fifi omo dogo
- Ohun elo fun ise agbe ni ___(a) ibon (b) ada (d) ofa
IPIN KEJI: Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
A. Ko oruko awon awo wonyi nine de geesi
i. Awo pupa – _____________________ (2) Awo olomi aro – _____________________
iii.Awo dudu – ______________________ (iv) Awo funfun – ______________________
v. Awo eweko – _____________________
B. Ko awon onka wonyi ni nomba
i. Eejilelogoji – _____________________ ii. Eejilelaadota – _________________________
iii. Aarundinlogota – ___________________ iv. Ogota – ____________________________
v. Aadota – _________________________
D. Apeko
i. ____________________________________
ii. _______________________________
iii. ____________________________________
iv. _______________________________
v. ____________________________________
vi. _______________________________
vii. ____________________________________
viii. _______________________________
ix. ____________________________________
x. _______________________________
Third Term Yoruba Examination Question for Primary School
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KERIN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Oriki orile yato si oriki ilu (a) beeko (b) beeni (d) n ko mo
- Kini ogota ni nomba (a) 50 (b) 70 (d) 60
- Okan lara awon ohun ti o maa n han ninu oriki ilu ni ___(a) orisa ilu (b) awo (d) ilu
- Apeere oro oruko aseeka ni ___(a) aga (b) oyin (d) omi
- Omo olofa mojo , olalomi omo abisu joruko awon iran wo ni a n ki bayi? (a) oluoje (b) olofa (d) opomulero
- Kemi sun fonfon, kini oro oruko ninu gbolohun naa? (a) sun (b) fonfon (d) kemi
- Okan lara apeere aroko ni ___(a) aroko alapejuwe (b) aroko onikalamu (d) aroko Oba
- Ijamba moto to soju mi je aroko ___(a) aroko onileta (b) aroko oniroyin (d) aroko ajiroro
- Ohun ti ko dara ti a ko gbodo se ni a n pe ni ___(a) eewo (b) ere ayo tita (d) ere owo
- Tani o fi omo re rubo fun odo Esinmiri? (a) Moremi (b) Tinubu (d) Ajayi Crowther
- Odun wo ni a bi Obafemi Awolowo (a) 1909 (b) 1910 (d) 1991
- Tani o se atunko bibeli lati ede geesi si ede Yoruba (a) moremi (b) Ajayi Crowther (d) Mosudi
- Tani obinrin akoko ti o koko wa oko mi orile ede Naijiria (a) olufunmilayo Kuti (b) Moremi (d) Efunroye
- Ilu ibo ni efunroye Tinubu pada si, leyin ti o kuro ni ilu Eko (a) Ijebu (b) Abeokuta /Egba (d) Ijanikin
- Meloo ni ami ohun ti o wa (a) meje (b) mejila (d) meta
- Ilu ti o wa fun gbogbo ayeye ni (a) dundun (b) agere (d) seli
- Kini Aadorin ni nomba? (a) 80 (b) 90 (d) 70
- Kini a n pe Ojo Abameta ni ede geesi? (a) Tuesday (b) Saturday (d) Monday
- Owara ni a pe ni ____ni ede geesi (a) November (b) January (d) October
- Idakeji olowo ni ____(a) olode (b) Talaka (d) amugo
- Itumo ile eko aladaani ni ile eko____ (a) olowo (b) nla (d) ti ki I se ijoba lo ni
Ninu iwe kika Ajoke se bebe
- Agogo meloo ni alaga ojo naa de? (a) mesan-an (b) mewaa ku iseju mewaa
(d) mewaa ku iseju marun
- Meloo ni awon akekoo ti n jade lo (a) ogorun (b) aadota (d) ogoji
- Apapo ebun ti Ajoke Akanji gba ni ojo naa ko din ni ____ (a)mewa (b) mejo (d) mejila
- Kini Ajoke se, ti won fi so pe o se bebe? (a) Ajoke ni o gba ebun ti o po ju
(b) Ajoke sun (d)Ajoke salo
NInu itan aworawo ko kan tise
- Asiko wo ni aworawo maa n de oko olowo re (a) owuro (b) osan (d) irole
- Kin o sele lojo kan ti o n ko ebe? (a) o ri oru owo (b) o ri kinun (d) o ri ejo
- Owo ti aworawo ri to elo (a) ogofa naira (b) ogoji naira (d) ogorun naira
- Kin ni Aworawo se si owo owo naa? (a) o gbe salo (b) ko fowo kan (d) o gbe owo naa lo fun ola ti I se olowo re
- Kin ni o sele si Aworawo ni igbeyin? (a) o ku (b) o di oba (d) o di ole
IPIN KEJI : Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:
A. Ko awon onka wonyi ni nomba
i. Eetalelogota = _______________________
ii. Aadorin= __________________
iii. Ookanlelaadota = ___________________________
iv. Aarundinlogota = _______________________
v Aadota = _______________________________
B. Daruko akoni ile Yoruba marun
i. ________________________________ ii. ________________________
iii. _______________________________ iv. ________________________
v. _________________________________
D. Di alafo wonyi pelu oro ti o bamu ni isale
i. Eni ti ko ni ewa rara _____
ii. Eni ti o maa n Daraya si enikeji _______
iii. Eni ti ko ni Igberaga rara ni ________
iv. Oro ti o lodi si ologbon ni ____________
v. Omo ti o n na owo ni inakunaa ni _____
(oloyaya, apa, oburewa, omugo, onirele)
Third Term Yoruba Examination Question for Primary School
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KARUN-UN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Aroko alariyanjiyan maa n da lori ______ (a) ise sise (b) iyan jija (d) ija jija
- Apeere oro oruko alaiseeka ni____(a) iyo (b) aga (d oluko
- Eniyan meloo ni o maa n ta ayo? (a) eniyan kan (b) eniyan meji (d) eniyan mewa
- Kini itumo foju lounje> (a) woran (b) gba oju mogi (d) foju
- Ise ni ____ise (a) oogun (b) bata (d) igo
- ____je apeere is ajumose (a) ona yiye (b) dida ilu ru (d) ole jija
- Omo ayo meloo ni o maa n wa ninu iho opon ayo kookan? (a) mefa (b) merin (d) meta
- ____je apeere oro aropo oruko (a) Jide (b) Awa (d) Aja
- Alaafin ni Oba ilu _____(a) Oyo (b) Oye (d) Oyan
- Ipinle meloo ni a ti lee ri aafin awon Oba alade ile Yoruba (a) meje (b) mefa (d) mejo
- Omo ayo meloo ni o wa ninu opon ayo lapapo? (a) Eejidinlaadota (b) Eejidinlogoji (d) (d) Ookanlelogun
- Kini owe wa fun? (a) ikilo (b) itanje (d) ise iyanu
- Anfaani ere ayo ni wipe , o maa n ____(a) je ki eniyan mo isiro (b) o maa n da opolo eniyan ru (d) o maa n dekun iba
- Apeere oro oruko aseeka ni ____(a) Tabili (b) suga (d) oyin
- “Juba ehoro” tumo si ___(a) salo (b) subu (d) sun
- Osu meloo ni o wa ninu odun? (a) osu meta (b) osu meji (d) osu mejila
- Ohun elo fun oge sise ni (a) alubosa (b) laali (d) Karosini
- Apeere ounje ile Yoruba ni ___(a) amala (b) semo (d) indomi
- Apeere oro oruko eran ko ni ___(a) pako (b) ewure (d) Amuga
- Tani olori ilu? (a) oluko (b) olopa (d) oba
- Aleebu ere ayo ni ___ (a) o maa n fi akoko sofo (b) o maa bu kun ewa wa (d) omaa n je ki ori pe
- Ipinle wo ni Ikeja wa? (a) ipinle oyo (b) ipinle eko (d) ipinle osun
- Orisii ise meloo ni a menuba ninu eko wa? (a) mefa (b) marun-un (d) merin
- Irinse agbe ni (a) oko (b) pakute (d) ibon
- Orisii agbe meloo ni o wa ___(a) meji (b) mefa (d) merin
- ____ ni o maa n ro ibon (a) ode (b) alagbede (d) akope
- Kini oruko ti a n pe awon onilu? (a) Ayan (b) olugbon (d) areas
- ____ni o maa n lo oko (a) ode (b) akope (d) agbe
- Ode ati ____ni o maa n to ofa (a) jagunjagun (b) onilu (d) agbe
- Ohun elo idana wo ni a maa fi n gbadura fun oko ati iyawo pe, won yoo bi omo pupo? (a) isu (b) iyo (D) ataare
IPIN KEJI: Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
A. Ko apeere oro-oruko aseeka marun-un
i. ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
v. ____________________________________
B. Ko apeere oro-oruko alaiseeka marun-un
i. ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
v. ____________________________________
D. so oruko ilu awon oba alade wonyi
i. ooni – ___________________________ii. Deji – ___________________________
iii. Oba – ___________________________iv. Olubadan -__________________________
v. Timi – ___________________________vi. Ataoja – ___________________________
vii. Ewi – __________________________ viii. Alake – _________________________
ix. Osemowe- _______________________x. Emia – _____________________________
E. So ona marun ti awon okunrin ile Yoruba n gba se oge
i. ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
v. ____________________________________
Third Term Yoruba Examination Question for Primary School
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KEFA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Itumi aropo lede geesi ni ____(a) subtraction (b) division (d) addition
- ____ni apeere oge sise laarin awon okunrin ni aye atijo (a) irun gige (b) laali lile (d) irun didi
- Okan lara aso okunrin ile Yoruba ni ___(a) agbada (b) tobi (d) gele
- Kin ni oro-ise ninu gbolohun yii Agbeke lo si oja (a) Agbeke (b) oja (d) lo
- Eebu alo ni ti ahun , abo bi ti ____(a) omo (b) ana (d) iyawo
- ______ni ege oro ti o lee ba eemi jade leekan soso (a) faweli (b) silebu (d) owe
- Kin ni o se Pataki julo ninu ohun elo idana (a) owo ori iyawo (b) obi (d) isu
- Kin ni ohun elo idana ti won fi n gbadura fun oko ati iyawo pe won maa bi omo pupo? (a) obi (b) orogbo (d) ataare
- Iro faweeli meloo ni o wa? (a) meji (b) meta (d) mewa
- Ami iro ohun meloo ni o wa? (a) meji (b) mefa (d) meta
- Kin ni oruko oba ile-ife (a) ooni (b) deji (d) ataoja
- Meloo ni leta faweeli airanmupe (a) leta meje (b) leta kan (d) leta mewa
- Leta faweeli aranmupe meloo ni o wa? (a) marun-un (b) mejila (d) mewa
- Apeere oro aponle ni ___(a) ropoto (b) sare (d) jeun
- ___je oruko amutorunwa (a) aina (b) bosede (d) joke
- Apeere asa oge sise ni ____(a) eyin pipa (b) moto wuwa (d) ile kiko
- A maa n fi ede ____(a) gbadura (b) jeun (d) gbale
- Tani olori ebi? (a) baba (b) egbon (d) iya
- Ojuse obi ni lati ____(a) pa omo won (b) toju omo won (d) fi iya je omo won
- Ise ijoba dara ju ise aladaani lo je aroko (a) oniroyin (b) asapejuwe (d) alariyanjiyan
- ____ni lilo ede tabi ami lati gbe ero okan eni jade (a) idanuro (b) ibara-eni soro (d) ala lila
- ___ni iye ona ti a n gba baa eni soro (a) meta (b) merin (d) marun-un
- Ewo ni o yato ninu awon ona ibara eni soro yii? (a) telifoonu (b) aale pipa (d) aroko
- Apeere ona ibara eni soro nipa lilo ohun elo olohun ni ___(a) oju (b) patako (d) ilu
- Aroko ni ___(a) ise to ni itumo akanlo (b) ise ti ko ni itumo (d) ise ti o le
- ______ni awon ti o lowo maa n lo fun irin ajo ni aye atijo (a) esin (b) ese (d) kanako
- Awon _____ni o maa n lo esin laye atijo (a) agbe (b) ode (d) olola
- _______ni o yato laarin awon wonyi (a) Baalu (b) Alupupu (d) Esin
- ______ni alagbede ma n fi finna (a) iwana (b) ewiri (d) emu
- Ohun ti awon alagbede fi maa n mu irin gbigbona ni (a) emu (b) ewiri (d) omo owu
Ipin keji: DAhun gbogbo awon ibeere wonyi.
A. Daruko marun ninu ohun elo ibara eni soro ni aye atijo
i. ____________________________________
ii. ___________________________________
iii. ___________________________________
iv. ___________________________________
v. ____________________________________
B. Daruko marun ninu ohun elo ibara eni soro ni aye ode oni
i. ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
v. ____________________________________
D. Pin awon oro wonyi si silebu
i. Aderibigbe – _________________________
ii. Agbalagba- _______________________
iii. Jegede – ____________________________
iv. Agbabiaka – ________________________
v. Alagbede- ____________________________
E. Daruko ounje abinibi ile Yoruba marun-un
i. ____________________________________
ii. ___________________________________
iii. ___________________________________
iv. ___________________________________
v. ____________________________________
E. Daruko aso ile Yoruba marun-un
i. ____________________________________
ii. ___________________________________
iii. ___________________________________
iv. ___________________________________
v. ____________________________________
G. ko leta faweeli aranmupe marun-un
i. ____________________________________
ii. ___________________________________
iii. ___________________________________
iv. ___________________________________
v. ____________________________________






