SECOND TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA SS2

Senior Secondary School Curriculum Yoruba – Edudelight.com

NERDC Curriculum Yoruba SS2

SS2 Second Term Yoruba Curriculum Lagos State

OSE 1

EDE – Aroko (Leta gbefe)

  1. Awon eto ati ilana leta gbefe
  2. Adiresi ikini, deeti, koko oro, asokagba ati bee bee lo

ASA – Isinku ni ile Yoruba I

  1. Orisirisi bii iku se n pani apeere, aisan, ijamba lorisirisi, afomowofe ati bee bee lo
  2. Itufo ati itoju oku ni ile Yoruba
  3. Ibanikedun ati sise oku agba

LITIRESO – Asayan iwe litireso ti ajo WAEC/NECO yan ti egbe akomolede ipinle Eko fi owo si

OSE 2

EDE – Aayan ogbufo

  1. Titumo ayolo ewi ni ede geesi si ede Yoruba
  2. Awon offin to ro mo aayan ogbufo

ASA – Isinku ni ile Yoruba II

  1. Orisirisi oku ati bi a se n sin won
  2. Oku omode (b) Oku obinrin (d) Awon oku abami
  3. Oku riro ati etutu oku sise bi ti elegun ba ku, won gbodo se etutu fun un ki eegun si jade lojo naa

LITIRESO – Itupale lori iwe Litireso ti ajo WAEC/NECO yan fun SS2

  1. Awon eda itan
  2. Ibudo itan

OSE 3

EDE – Aayan ogbufo oloro wuuru:

  1. Titumo eyo oto gbolohun ede geesi si ojulowo ede Yoruba
  2. Titumo ayolo ipin afo lati ede geesi si ede Yoruba

ASA – Eto ogun jije I

  1. Itumo ogun ati ohun ti an je logun
  2. Iyato laarin ogun iya ati baba
  3. Ona ti a n gba pin ogun ni ile Yoruba
  4. Awon ti o ni eto si ogun pinpin
  5. Aleebu to rom o ogun pinpin

LITIRESO – Itupale iwe litireso: Ahunpo itan ati asa Yoruba to suyo ninu itan naa

OSE 4

EDE – Aroko (leta aigbagbefe)

  1. Igbese leta aigbagbefe
  2. Adiresi, deeti, ikini, akole, koko oro, ikaadi, oruko ati ifowosi

ASA – Eto ogun pinpin II

Ipa ti ofin ijoba n ko lori ogun laye ode oni

LITIRESO – Sise itupale asayan iwe litireso:

  1. Awon ilo ede lakanlo ede
  2. Sise orinkinniwin won

OSE 5

EDE – Iparoje ati isunki:

  1. Pipa iroje ibi ti ipaje yii ti le waye apola oruko apola ise ati awon ihun miiran

ASA – Eto idajo laye atijo:

  1. Ona ti a fi n se idajo laye atijo beere lati odo oba, baale ati ijoye
  2. Ipa ti emese / ilari n ko ninu eto idajo

LITIRESO – Kika iwe asayan ti ajo WAEC/NECO yan

OSE 6

EDE – Aranmo:

  1. Itumo aranmo
  2. Orisii aranmo
  3. Ofin to ro mo aranmo

ASA – Eto idajo lode oni:

  1. Idajo lode oni ni ile ejo orisirisi, ile ejo ibile, ile ejo giga, ile ejo kotemilorun, ile ejo togajulo igbimo, eleti gbaroye ati beebee lo
  2. Ipa ti olopaa ati woda n ko ninu idajo ode oni
  3. Ise agbejoro ninu idajo odeoni
  4. Eto yiyanju aawo lori redio ati telifison

LITIRESO – Kika sayan iwe litereso Yoruba ti ijoba yan

OSE 7

EDE – Oro agbaso:

  1. Afo asafo
  2. Afo agba oro
  3. Awon wunren ti maa n lo ninu oro agbaso

ASA – Aroko pipa:

  1. Orisirisi awon n kan ti a fin paroko ati itumo won
  2. Idi/anfani ti a fin paroko ni ile Yoruba

LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan

OSE 8

EDE – Oro/gbolohun onipoona:

  1. Itumo poona
  2. Akojopo awon oro onipoona
  3. Alaye lori itumo oro ati gbolohun onipoona

ASA – Eewo ni ile Yoruba:

  1. Kini eewo/orisi eewo
  2. Orisirisi eewo ati itumo okankan won
  3. Ki ni o maa n sele ti eniyan ba deja eewo ati atunbo tan re

LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan

OSE 9

EDE – Awe gbolohun ede Yoruba:

  1. Oriki ati alaye kikun lori awe gbolohun
  2. Orisi awe gbolohun
  3. Olori awe gbolohun
  4. Awe gbolohun afarehen

ASA – Igbagbo ati ero Yoruba nipa Ajinde leyin iku

LITIRESO – Awon eka ede Yoruba:

  1. Ohun ti eka ede je

Awon eka ede to wan i ipinle kookan

OSE 10

EDE – Apola ninu gbolohun ede Yoruba:

  1. Apola oruko
  2. Apole ise
  3. Ihun apola
  4. Awon isori oro ti a le ba pade labe apola oruko ati apola ise

ASA – Igbagbo Yoruba nipa Olodumare:

  1. Tani Olodumare?
  2. Awon oruko ti Yoruba fi n pe Olodumare
  3. Abuda ti awon Yoruba fi n pe Olodumare

LITIRESO – Kika iwe ti ijoba yan

OSE 11 – Atunyewo lori gbogbo ise saa yii

OSE 12 & 13 – Idanwo ipari saa yii

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button