FIRST TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA JSS 2 (Basic 8)

Junior Secondary School Scheme of work Yoruba – Edudelight.com

NERDC Curriculum Yoruba JSS2

JSS2 First Term Yoruba Scheme of work Lagos State

ISE OOJO FUN SAA KIN-IN-NI

Week 1 – Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba

  • Atunyewo awon asa ninu ise olodun kin-in-ni
  • Atunyewo awon ewi alohun yoruba

Week 2 – Eya gbolohun nipa ise won

  • Asa igbeyawo ni ile Yoruba
  • Kika iwe apileko ti ijoba yan

Week 3 – Eya gbolohun

  • Asa igbeyawo ni ile Yoruba (igbeyawo ode-oni)
  • Kika iwe apileko oloro geere

Week 4 – Gbolohun ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o

  • Sise akanse ise awujo Yoruba (project)
  • Litireso alohun to je mo ayeye

Week 5 – Onka Yoruba (101-300)

  • Ise akanse kan ni awujo (project)
  • Litireso alohun to je mo ayeye
  • Kika iwe apileko ti ijoba yan

Week 6 – Onka Yoruba (300-500)

  • Sise itoju oyun ni ona abinibi ati ode-oni

Week 7 – Akaye oloro geere

  • Ise omo bibi (oro idile baba olomo)
  • Kika iwe apileko ti ijoba yan

Week 8 – Akaye oloro geere

  • Asa isomoloruko
  • Kika iwe apileko ti ijoba yan

Week 9 – Akoto

  • Igbagbo Yoruba nipa orisirisi owe ile Yoruba
  • Kika iwe apileko oloro geere ti ijoba yan

Week 10 – Kiko Yoruba ni ilana akoto ode-oni

Orisirisi oruko ile Yoruba (igbagbo Yoruba nipa abiku)

One Comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button